E Tun Le Se Ju Be Lo O (CCCS)

preview_player
Показать описание
LYRICS: E TUN LESE JUBE LO O
Gangan: « Asee se tun se, Asee se tun se
bi o ba seyi tan, wa tun se mi si,
Asee se tun se »

Chorus: (2ce)
E tun lese jube lo o
B'ese se l'ojo si
L'eti okun pupa
Omi tun jade lati 'nu apata
Baba e tun se leekan si.
Interlude:
Asee se tun se, Asee se tun se
bi o ba seyi tan, wa tun se mi si,
Asee se tun se

Bridge: (2ce)
Kale soro ogo re
L'aarin awon keferi
Kale royin ise iyanu
L'aarin gbogbo eniyan
Nitori t'o tobi o
Ju orisa lo
Nitori t'o tobi o
Ju orisa lo

Verse:
Baba jewo ara re
K'araye le mon wipe e ire nikan l'Oba
Baba jewo ara re
K'araye le mon wipe e ire nikan l'Oba
Araye ma n bere oo
Eniyan ma n bere oo
Won so wipe ogo atijo nko
We wanna walk in the path as of old
Coz we need glory as of old
Baba jewo ara re
K'araye le mon wipe e ire nikan l'Oba

Interlude...

Chorus: (2ce)
E tun lese jube lo o
B'ese se l'ojo si
L'eti okun pupa
Omi tun jade lati 'nu apata
Baba e tun se leekan si Interlude

Bridge: (2ce)
Kale soro ogo re
L'aarin awon keferi
Kale royin ise iyanu
L'aarin gbogbo eniyan
Nitori t'o tobi o
Ju orisa lo
Nitori t'o tobi o
Ju orisa lo
Nitori t'o tobi o
Ju orisa lo.
END!
Рекомендации по теме