Monday Motivation: Ise Logun Ise

preview_player
Показать описание
This poem is a reminder that success doesn't come easy. It takes hard work, dedication, and perseverance.

Don't waste your time, work hard and plan for the future because hard work is the key to success.

Challenge yourself today to become useful to yourself and the society!
Рекомендации по теме
Комментарии
Автор

IṢẸ́ L'ÓÒGÙN ÌṢẸ̀Ẹ́

1) Mú'rá sí iṣẹ́ ẹ̀ rẸ́, ọ̀rẹ́ ẹ̀ mí

Iṣẹ́ ní ns'ọ́'ní d'Ẹ́ní gígá

Bí á kò bá r'Ẹ́ní fẹ̀hìn tì

Bí ọ̀lẹ́ l'àárí
Bí á kò r'Ẹ́ní gbẹ́kẹ̀lé
Á tẹ́'rá mọ́' ṣẹ́ ẹ́ Ẹ́ní


Ìyá à rẹ́ lè l'ówó l'ọ̀wọ́
Bàbá à rẹ́ ṣì lè l'eṣín l'Èèkàn (L'ẹ́ṣín l'Éèkàn- has horses in the stable)
Bí Ó bá gb'ójú lé Nwọ́n
Ó tẹ́ tán ní mó sọ́ fún Ọ́!
Ṣ' óhún tí á kò bá j'ìyà fún ún
Iyẹ́n kì í t'ọ́jọ́
Ọ̀hún tí Á bá f'árá ṣ'íṣẹ́ fún
Ní npẹ́ l' lọ́wọ́ Ẹ́ní

Apá l'árá, igúnpá n' Íyèèkàn (íyèèkàǹ- relative)
Bí Aiyé bá fẹ́ Ọ́ l'ónì í
Bí Ó bá l'ówó l'ọ́wọ́, nwọ́n á tún fẹ́ Ọ́ l'ọ́lá
Tábí kí Ó wà n'ípó àtàtà,
Aiyé a yẹ́ Ọ́ sí t'ẹ̀rín-t'ẹ̀rín
Jẹ́ kí Ó d'Ẹ̀ní tí nráágó
Kí Ó wá wó bí nwọ́n yíó tí má á yín'mú sí Ọ́
Ẹ̀kọ́ ọ́ sì nsọ́'ní d' Ọ̀gá á
Yáá'rá kí Ó kọ́ ọ́ dárá-dárá
Bí Ó sì rí ọ̀pọ̀ èníà
Tí ń fi ẹ̀kọ́ ṣ' ẹ̀rín rín
Dá'kún, má f' árá wé nwọ́n
Ìyá mbẹ́ f'ọ́mọ́ tí kò gbọ́n
Ẹkún mbẹ́, f'ọ́mọ́ tí ń sá kírí
Má f'òwúrọ́ ṣ'éré Ọ̀rẹ́ ẹ́ mí

Mú'rá s' íṣẹ́, ọ́jọ́ nlọ́




2) Já itánnà t'ó ntàn

T'ó tútù t'ó sì dárá

Má dùró d'ọ́jọ́ ọ̀lá

Àkókó ńsáré tété

ronkebarber